HYMN 101

11S A.M.1. AIKU, Airi, Olorun ogbon gbogbo

   O ngbe'nu imole, be l'o farasin

   Olubukun julo, A yin oruko Re.


2. L’aisimi, L'aikanju, O dake roro

   Nin‘oro, l'aosofo, O njoba ni’pa

   Ododo Re ga ju awon oke lo

   Kuuku Re j'orisun ire ati 'fe.


3. O mbukun fun eniyan, t‘omode,

   t’agba

   lgbe aye ‘rorun l'o fi fun eda

   A ngba bi itannna eweko tutu

   A nwa, ti l’a si nku

   'Wo ko yi pada.


4. Oba mi Ologo, Mimo ‘nu imole

   Awon angel yin O, won bo oju won

   Awa na y'o yin O, bi awon t'orun

  Ogo imole l‘o pa O mo fun wa. Amin

English »

Update Hymn