HYMN 102

8.8.8.8.8.8.6.6.6.61. E YO loni pe l‘ohun kan

   E korin igbega soke

   E yo, eyin Oluwa wa

   T'apa Re mu igbala wa

   lse Ife npokiki

   Titobi oruko Re

   Olorun kan laelae

   To ti f'anu Re han

   K'eniyan mimo Re juba Re.


2. Gba banuje de, a kepe

   O si gbo gbogbo ‘aroye wa

   Gbekele boti wu kori

   Agbeniro ni ife Re

   Orin iyin ‘segun

   Lokan wa y’o ko si

   Gbogb’ohun y'o ko pe

   ‘E yin Olorun wa

   K’eniyan mimo re juba Re.


3. E yo, loni pe l’ohun kan

   E korin igbega soke

   E yo, eyin Oluwa wa

   T’apa Re mu igbala wa

   Ise Ife npokiki

   Totibi oruko Re

   Olorun kan laelae

   To ti f‘anu Re han

   K'eniyan mimo Re juba re. Amin
 

English »

Update Hymn