HYMN 106

8.8.8.51. YIN Oluwa, enyin mimo

   Awa ti je ni ‘gbese to?

   Je k'a mu gbogbo ini wa

   Wa pelu ayo.


2. Jesus l'Oko t'o dara ju

   O nfun wa l'okun l'oju ‘ja

   lbi kan ko le de ba wa

   ‘Gbat‘ a gbekele.


3. Gbekele yin le, eyin mimo

   Olododo l’Olorun wa

   Ko s'ohun to le, ya awon

   T‘O fe l‘odo Re.


4. F'ore ofe Re pa wa mo

   K‘a le tubo faramo O

   Titi ao fi de ‘nu ogo

   At‘ ayo l‘orun.


5. ‘Gbana l‘ ao de ibi mimo

   ‘Gbana l'a o si di mimo

   Ayo nla ti a ko so

   Ni y‘o je ti wa. Amin

English »

Update Hymn