HYMN 108

Tune: Children of Jerusalem1. KERUBU ati Serafu

   E fun irugbin rere s‘aiye

   Enyin l’a pe Iati s' awon

   Ti yio pade Oluwa l'oke.

Egbe: Gbo, gbo, gba b'awon

      Serafu ti nke

      Gbo, gbo, gbo b’awon

      Kerubu ti nke

      Halleluyah, Halleluyah,

      Halleluyah, f’Oba wa.


2. Onigbagbo, e ji giri,

   K’a fi iwa ese s'ile

   K’a se ife Oluwa wa,

   K'a Ie r'oju rere Olorun.

Egbe: Gbo, gbo...


3. Onigbngbo, e gb'adura

   E fi okan funfun sise

   E gb' awe pelu iwa mimo

Egbe: Gbo, gbo...


4. Enyin araiye, e tun aiye se

   Fun bibo Jesu Oluwa

   K'ese dinku, k’ajakale aron

   Ma ti wa lo s‘orun apadi.

Egbe: Gbo, gbo...


5. Onigbagbo beru Olorun

   Feran Omonikeji re

   Mase pegan mase binu

   Olorun yio gbo adura re.

Egbe: Gbo, gbo...


6. Opo idanwo l’o wa l’aiye

   Sugbon eyi t’o buruju

   K’a ma r’owo, k’aisan de ni

   JAH jowo ma fi eyi se wa.

Egbe: Gbo, gbo, gba b'awon

      Serafu ti nke

      Gbo, gbo, gbo b’awon

      Kerubu ti nke

      Halleluyah, Halleluyah,

      Halleluyah, f’Oba wa. Amin

English »

Update Hymn