HYMN 112

1. YIN Olurapada re

F’Ogo f’oruko Re titi lae 

Oloto li on sa je.

Egbe: F'ogo f’oruko Re titi lae

Gb 'oruko re ga! F'ogo f’oko Re 

Korin Aleluya titi lai

Gb'oruko re ga! Fogo f’oko Re! 

Korin ‘yin s’Oluwa titi lae.


2. Fun ‘bukun to nfi fun wa 

F‘ogo f’oruko Re titi lae

B‘or’ofe Re ti po to.

Egbe: F'ogo f’oruko Re titi lae...


3. KO ha se o l'ore bi!

F‘ogo f'oruko Re titi lae! 

Kil'o ku k'O se fun o? 

Egbe: F'ogo f’oruko Re titi lae...


4. lfe wo lo po bayi

F'ogo f'oruko Re titi lae! 

Alafia bayi wa bi!

Egbe: Gb'oruko re ga!...


5. Ki ahon mi tu lati

F‘ogo f‘oruko Re titi lae 

K’emi Iat'ayeraye.

Egbe: Gb'oruko re ga!... Amin

English »

Update Hymn