HYMN 113

(FE 130)
"Okan mi yin Oluwa l'Ogo”1. Okan mi yin Oluwa l'Ogo 

   Oba iyanu to wa mi ri,

   Ngo gb’agogo iyin y'aiye ka, 

   Ngo fi iyin Atobiju han. 

Egbe: OIuwa 0pe ni fun O 

      Fun ore-ofe to fi pe mi

      Jesu di mi mu titi, dopin, 

      Ki nle joba pelu Re I'oke.


2. lru ‘fe ti Jesu fi pe mi, 

   Ohun iyanu l’o je fun mi, 

   Ona ti Jesu gba fi pe mi, 

   Ona ara l'o tun je fun mi. 

Egbe: OIuwa 0pe ni fun O... 


3. Ope wo l’awa Ie fun fun O, 

   Iwo Oba Egbe Kerubu,

   Fun ‘segun abo Re larin wa, 

   Fun anu at'ore Re gbogbo.

Egbe: OIuwa 0pe ni fun O... 


4. lwo ti o gba ope Noah, 

   Gb'ope iyin t‘a mu wa fun O 

   lwo ti o gb‘ore Abraham 

   Ma je k'ope wa k'o di ‘baje. 

Egbe: OIuwa 0pe ni fun O... 


5. Egbe Kerubu ati Serafu

   E ho, e yo si Oba Orun 

   Fun ‘se lyanu Re larin wa 

   Fun Ore Re alailosunwon. 

Egbe: OIuwa 0pe ni fun O... 


6. Ayo ni fun o l'ojo oni

   A f’Ogo fun baba at'Omo

   A f‘Ogo fun O Emi Mimo 

   Olojo oni gba ope wa.

Egbe: OIuwa 0pe ni fun O 

      Fun ore-ofe to fi pe mi

      Jesu di mi mu titi, dopin, 

      Ki nle joba pelu Re I'oke. Amen

English »

Update Hymn