HYMN 124

C.M.S 554, H.C 54, L.M (FE 141)
"E ho iho ayo si Oluwa, enyin ile
gbogbo - Ps. 100:11. NIWAJU ite, Jehovah,

   E f'ayo sin, oril’ede

   Mo p’Oluwa, on kanso ni 

   O le da, O si le parun.


2. lpa Re, laisi ‘ranwo wa, 

   L‘o f’amo da wa l’enia 

   Nigbat' a sako b’agutan 

   O tun mu wa si agbo Re.


3. A o f‘orin sunmo ‘le Re; 

   Lohun giga l'a o korin 

   Aiye l'oniruru ede

   Y’o f'iyin kun agbala Re.


4. Ase Re gboro b’agbaiye 

   Ife Re pe b’ayeraye

   Oto Re yio duro lailai 

   Gbat’ odun ki yio yipo mo. Amin

English »

Update Hymn