HYMN 125

(FE 142)
Tune: Mase sise lo L.M1. GBOGBO eda abe orun 

   E f’iyin fun Eleda wa, 

   Ki gbogbo orile-ede 

   Korin iyin Olugbala.


2. Oluwa, anu Re ki ti,

   Oto Re si duro lailai 

   Iyin Re y’o tan kakiri

   Tit'orun y’o la laiwo mo. Amin

English »

Update Hymn