HYMN 13

C.M.S 120, t.H.C 224, 7s (FE 30)
“Iwo ti ngbo adura, si odo re ni
gbogbo enia mbo" - Ps.65:2


1. A GBOJU soke si O,

   At'owo ati okan, 

   Tewo gba adura wa, 

   B'o tile se ailera.


2. Oluwa, je k'a mo O

   Je k'a mo oruko Re; 

   Je k‘awa si ife Re,

   Bi nwon ti nse Ii orun.


3. Nigbati a sun l’oru 

   So wa, k‘O duro ti wa

   Nigbati ile si mo 

   K‘a ji, k'a fi iyin fun O. Amin

English »

Update Hymn