HYMN 131

Tune: CM1. A k’orin s’Omo Olorun 

Odagutan t’a pa

Ti orun ati aye mbo 

T'O ye lati joba.


2. Si O l’awon Angeli nke 

   L'ekun gbogbo orun 

   Mimo mimo, mim'Olorun 

   T'ogo at’om'ogun.


3. ljo Re li aye dapo 

   Lati ma kepe O 

   Didan Olanlan Olorun 

   T'O l‘agbara gbogbo.


4. Larin won ni gbogbo wa nfe

   Lai yin eje re

   Joba l’aye ati l'orun

   Wo Omo Olorun. Amin

English »

Update Hymn