HYMN 135

(FE 152)1. E KE Halleluyah s’Oba lye, 

   To je ki odun soju emi wa, 

   K’esu tab’ese ma bi wa subu, 

   Ninu ona iye t’Oluwa pe wa si. 

Egbe: Yin Oba Ogo, Kerubu,

      Pelu Serafu ti Baba ti yan, 

      K’orin at' adura kun enu wa, 

      Jesu y’o ko wa de ’te ogo,

      A! e yo.


2. Baba, Omo, ati Emi Mimo

   E ma je koju at’owo nyin si, 

   L’arin Kerubu ati Serafu,

   Je ki ibukun Re k’o kari wa l’aiye. 

Egbe: Yin Oba Ogo...


3. Enyin Omo Egbe Kerubu yin,

   A si ki nyin ku ewu odun yi,

   E mura k'e si yo n’nu Oluwa,

   To d’emi nyin si d’ojo oni l‘anu Re. 

Egbe: Yin Oba Ogo...


4. Enyin Kerubu ati Serafu

   E mura k’e wa n’ife s’ara nyin, 

   Baba y’o si fun nyin n’ife toto, 

   Lati sise gegebi awon ti orun.

Egbe: Yin Oba Ogo, Kerubu,

      Pelu Serafu ti Baba ti yan, 

      K’orin at' adura kun enu wa, 

      Jesu y’o ko wa de ’te ogo,

      A! e yo. Amin

English »

Update Hymn