HYMN 142

1. Eyin Oba ogo, On ni Olorun 

   Yin I fun se yanu ti O fi han

   O wa pel’ awon ero mimo l'ona 

   O si je imole won l'osan l‘orun.

Egbe: Eyin angel didan lu duru wura

      Ki gbogbo nyin juba t'e nwo oju Re 

      Ni gbogbo 'joba Re, b'aye ti nyi lo 

      Ise Re y'o ma yin

      Ise Re y'o ma yin

      Fi ibukun fun Oluwa okan mi.


2. E yin fun ‘rapada, ti gbogbo okan 

   E yin fun orisun lmularada

   Fun inu rere ati itoju Re 

   Fun'daniloju pe O ngbo adura. 

Egbe: Eyin angel didan lu duru...


3. Eyin fun idanwo, bi okun ife

   T'o aso wa po mo awon ohun orun 

   Fun ‘gbagbo ti nsegun ‘reti ti ki sa 

   Fun ile Ogo t'O ti pese fun wa. 

Egbe: Eyin angel didan lu duru wura

      Ki gbogbo nyin juba t'e nwo oju Re 

      Ni gbogbo 'joba Re, b'aye ti nyi lo 

      Ise Re y'o ma yin

      Ise Re y'o ma yin

      Fi ibukun fun Oluwa okan mi. Amin

English »

Update Hymn