HYMN 147

ss 999 tHC 532 (FE 165) 
"Ogo fun Eniti' o fe wa”
- Ifi. 14:71. GBO orin eni irapada

   Orin iyin titun

   Nwon nyin Odagutan l'ogo 

   Nwon nkorin na bayi. 

Egbe: Ogo f ’Eni to fe wa,

      T'o f 'eje Re we wa, 

      Ti o si so wa di mimo 

      N’nu ibi iye ni.


2. A f‘oso wa n'nu eje e, 

   O si funfun laulau 

   ‘Mole t’O tan si okan 

   Nf' Ipa Oto Re han. 

Egbe: Ogo f ’Eni to fe wa...


3. Nipa agbara Eje Jesu 

   L’a fo ‘tegun Esu 

   Nipa agbara Oto Re, 

   La se bori ota. 

Egbe: Ogo f ’Eni to fe wa...


4. Je ka juba Odagutan

   T'o fun wa ni ‘imole

   Tire l'ogo at’agbara

   Olanla at‘lpa.

Egbe: Ogo f ’Eni to fe wa,

      T'o f 'eje Re we wa, 

      Ti o si so wa di mimo 

      N’nu ibi iye ni. Amin

English »

Update Hymn