HYMN 148

D7S6S1. IMOLE iyanu ntan

   Gba Kristien ba nkorin 

   Oluwa ni ngbe ni ro 

   lwosan n'n'apa Re

   ‘Gba olutunu jin‘na 

   O nfun okan ni‘simi 

   lmole otun y'o la 

   Nigba t'ojo si da.


2. Nigba t‘ero mimo nso 

   L‘ayo la‘wa nlepa 

   lgbala Olorun wa

   T’a si nri gba l‘otun

   O ngba wa n‘nu ‘banuje 

   Awa le f‘ayo wipe

   Je ki ola aimo de 

   Ohun t'o wun k'o je.


3. Ohunkohun t’o le de 

   Jesu y’o gba wa la 

   On t’o wo lili l'aso 

   Y’o fi aso wo wa

   L'abe orun t‘o teju 

   Ghogbo eda l’o nbo 

   On t‘o nbo eiye orun 

  Y’o bo aw’omo Re.


4. B'ajara tabi opoto

   Ko lati m'eso wa

   Bi gbogbo eweko gbe

   T’ agbo agutan s’egbe 

   Olorun wa mbe sibe 

   Iyin Re y’o kun enu mi 

   Bi mo gbekele E titi 

   Ayo y’o je t’emi. Amin

English »

Update Hymn