HYMN 150

ORIN lYlN (FE 168)1. OHUN t’Oluwa yio se

   Oba mi ko fi y’enikan. x4

Chorus: Awon enia pataki lo ti ku

       Opo enia pataki lo ti Io o

       Eda to ba wa laye, x4

       Ko wa fi iyin f'onise Nla. x3


2. Ore t‘Oluwa ba se 

   Ara mi jowo fi han o. x4 

Chorus: Awon enia pataki...


3. Ore t'Oluwa ba se 

   Ore mi jowo fi han o. x4 

Chorus: Awon enia pataki...


4. Omo l'Olorun fun o

   Ore mi jowo fi han o. x4 

Chorus: Awon enia pataki...


5. lke l’Olorun fun o 

   Ore mi jowo fi han o. x4

Chorus: Awon enia pataki...


6. Ohun t’Oluwa fun o

   Jowo fi yin Messiah o. x4

Chorus: Awon enia pataki lo ti ku

       Opo enia pataki lo ti Io o

       Eda to ba wa laye, x4

       Ko wa fi iyin f'onise Nla 

       Ko wa fi iyin f'onise Nla

       Ko wa fi iyin f'onise Nla. Amin

English »

Update Hymn