HYMN 153

(FE 172)
"Tali o dabi iwo Oluwa"
- Eks 15:111. TAL'eni na ti nkan 'lekun

   okan mi? 

   Tal'eni na ti nkan 'lekun

   okan mi? 

   Jesu Kristi Omo Olorun ni,

   S'ilekun je ko wole lo.


2. Tal'eni na ti nkan 'lekun

   okan mi? 

   Tal'eni na ti nkan 'lekun

   okan mi? 

   Emi Mimo adaba orun ni 

   S'ilekun je ko wole lo.


3. Tal'eni na ti nkan 'lekun

   okan mi? 

   Tal'eni na ti nkan 'lekun

   okan mi? 

   Olupese Oba awon Oba,

   S'ilekun je ko wole lo.


4. Tal'eni na ti nkan 'lekun

   okan mi? 

   Tal'eni na ti nkan 'lekun

   okan mi? 

   Olupese Oba aiyeraiye

   S'ilekun je ko wole lo.


5. Tal'eni na ti nkan 'lekun

   okan mi? 

   Tal'eni na ti nkan 'lekun

   okan mi? 

   Olusegun alabo mi ni

   S'ilekun je ko wole lo.


6. Tal'eni na ti nkan 'lekun

   okan mi? 

   Tal'eni na ti nkan 'lekun

   okan mi? 

   Jesu Kristi Oluwoye mi ni,

   S'ilekun je ko wole lo.


7. Tal'eni na ti nkan 'lekun

   okan mi? 

   Tal'eni na ti nkan 'lekun

   okan mi? 

   Jesu Kristi Omo Olorun ni,

   S'ilekun je ko wole lo. Amin

English »

Update Hymn