HYMN 154

(FE 173)
"A f’Emi Mimo lo le so ni d'alaye"1. A f'Emi Mimo lo le so ‘ni

   d’alaye (2ce)

   So 'ni d’alaye, so 'ni d’alaye,

   A f'Emi Mimo lo le so ‘ni d‘alaye.


2. Eni to ba ni Jesu o l’ohun

   gbogbo (2ce)

   O l'ohun gbogbo, o l’ohun gbogbo 

   Eni to ba ni Jesu o l‘ohun gbogbo 

   Eni to ba ni Jesu o l‘ohun gbogbo 

   Jesu Kristi lo ns'olori ohun 

   gbogbo (2ce)

   Eni to ba ni Jesu o l’ohun gbogbo.


3. Opo ibukun l'adura mu ba ni l’aiye (2ce)

   Mu ba ni l'aiye, mu ba ni l’aiye, 

   Opo ibukun l‘adura mu ba wa l’aiye

   Lai ke pe E asan I‘awa je (2ce)

   Opo ibukun l'adura mu ba ni l’aiye. Amin

English »

Update Hymn