HYMN 155

S.S 753 (FE 174) 
"Sugbon e ko alikama sinu aba mi" 
- Matt.13:301. Enyin Olukore ‘nu oko 

   T’o ro t‘o si ndaku

   E wa duro de Olugbala 

   Yio so agbara wa d’otun. 

Egbe: Awon to duro d'Oluwa

      Y'o tun agbara wion se

      Nwon o fi iye fo bi idi

      Nwon o sore nwon ki yio daku 

      Nwon o sore nwon ki yio daku 

      Nwon o rin ki yio re won 

      Nwon o rin ki yio re won 

      Nwon o sore nwon ki yio daku 

      Are ki yio mu won. 


2. ldaku at‘are ‘gbakugba

   Nrnu wa lati ma kun

   B‘a ba mo p’Olugbala wa mbe 

   Ese ti yio fi re wa?

Egbe: Awon to duro d'Oluwa...


3. E yo fun pe O mba wa gbe po 

   Ani titi d’opin,

   W‘oke fi ‘gboiya tesiwaju 

   Y'o ran 'ranwo Re si wa.

Egbe: Awon to duro d'Oluwa

      Y'o tun agbara wion se

      Nwon o fi iye fo bi idi

      Nwon o sore nwon ki yio daku 

      Nwon o sore nwon ki yio daku 

      Nwon o rin ki yio re won 

      Nwon o rin ki yio re won 

      Nwon o sore nwon ki yio daku 

      Are ki yio mu won. Amin

English »

Update Hymn