HYMN 156

A & M. 212. 8.8.6 (FE 175)
“Olutunu na, ti se Emi Mimo, on ni o ko
nyin li ohun gbogba" - John 14:261. SI O olutunu Orun

   Fun ore at'agbara Re,

   A nko Alleluya.


2. Si O, ife enit‘ o wa,

   Ninu Majemu Olorun

   A nko Alleluya.


3. Si O ohun eniti npe 

   Asako kuro ninu ese, 

   A nko Alleluya.


4. Si O, agbara eniti

   O nwe ni mo, t'o nwo ni san 

   A nko Alleluya.


5. Si O, ododo Eniti 

   Gbogbo ileri Re je ti wa 

   A nko Alleluya.


6. Si O, Oluko at’Ore 

   Amona wa toto d’opin 

   A nko Alleluya.


7. Si O, Eniti Kristi ran

   Ade on gbongbo ebun Re, 

   A nko Alleluya.


8. Si O, Enit’o je okan 

   Pelu Baba ati Omo

   A nko Alleluya. Amin
 

English »

Update Hymn