HYMN 157

S.S. 686 (FE 176)
"E je alagbara ninu Oluwa" 
- Efe. 6:101. J’ALAGBARA n‘nu

   Krist, ati pa agbara Re

   Duro sinsin f’otito oro Re

   Y’o mu o koja lo larin

   ogun to gbona

   ‘Wo y‘o segun l‘Oruko Oluwa, 

Egbe: Duro gbonyin, f‘otito

      Lo si 'segun Ii ase Oba

      Fun Ola Oluwa Re ati

      ‘segun oro Re,

      Duro gbonyin I'agbara Oluwa.


2. J‘alagbara n'nu Kristi ati

   ‘pa agbara Re.

   Mase pehinda niwaju ota

   Yio duro ti o b’o ti nja fun Otito 

   Te siwaju n’nu ‘pa agbara Re.

Egbe: Duro gbonyin, f‘otito...


3. J'alagbara n‘nu Kristi

   ati ‘pa agbara Re,

   ‘Tori ‘leri Re ki yio ye lai

   Yio dowo re mu gbat‘o

   nja fun otito

   Gbekele wo o ma segun lailai

Egbe: Duro gbonyin, f‘otito

      Lo si 'segun Ii ase Oba

      Fun Ola Oluwa Re ati

      ‘segun oro Re,

      Duro gbonyin I'agbara Oluwa. Amin

English »

Update Hymn