HYMN 158

6.8s (FE 177) 
Tune: Oluwa yio pese
“lye awon ti a fi Emi Mimo to, awon 
ni ise Omo Olorun" - Rom. 8:141. FUN mi ni Emi Mimo 

   EMI MIMO Baba,

   Eyi ni mo ntoro, Oluwa o 

   Fun mi ni EMl MIMO

   Ki nma lo n’n agbo Re 

   Titi Jesu yio fi de.


2. Fun mi ni agbara,

   Ni agbara, Baba

   Eyi ni mo ntoro, Oluwa 

   Fun mi ni agbara

   Ki n,ma lo nin' agbo Re 

   Titi Jesu yio fi de.


3. F‘epo s’atupa mi, 

   S‘atupa mi, Baba

   Eyi ni mo ntoro, Oluwa 

   Fun mi ni agbara

   Ki nma lo nin’agbo Re 

   Titi Jesu yio fi de. Amin

English »

Update Hymn