HYMN 16

P.B. C.M.S 23, 9s 8s (FE33)
"Ise won ni lati duro lororo lati
dupe, ati lati yin Oluwa, ati be 
gege Ii asale” - 1 Kron. 23:30


1. OLUWA, ojo t'o fun wa pin

   Okunkun si de l‘ase Re, 

   ‘Wo l'a korin owuro wa si, 

   lyin Re y'o m'ale wa dun.


2. A dupe ti Ijo Re ko nsun, 

   B’aiye ti nyi lo s'imole

   O si nsona ti gbogbo aiye 

   Ko simi tosan-toru.


3. B'ile si ti mo lojujumo 

   Ni orile at'ekusu

   Ohun adura ko dake ri, 

   Be l’orin iyin ko dekun.


4. Orun t‘o wo fun wa, si ti la 

   S‘awon eda iwo-orun 

   Nigbakugba li enu si nso 

   lse ‘yanu Re di mimo.


5. Be, Oluwa, lai n’ijoba Re, 

   Ko dabi aiye

   O duro, o si nse akoso

   Tit' eda Re o juba Re. Amin


English »

Update Hymn