HYMN 163

 (FE 182)
"Emi Olorun sokale bi adaba" - Matt 3:161. ADABA Mimo sokale

   Ko wa fun wa ni agbara 

   Adaba Mimo sokale.


2. Adaba Mimo sokale

   Ko wa fun wa ni isegun 

   Adaba Mimo sokale.


3. Adaba Mimo sokale

   Ko wa fun wa ni Ibukun: 

   Adaba Mimo sokale.


4. Adaba Mimo sokale

   Sure fun wa l’ojo oni, 

   Adaba Mimo sokale. Amin

English »

Update Hymn