HYMN 166

‘Sugbon enyin yio gba agbara lehin
ti Emi Mimo ba le yin" - lse 1:81. AGBARA kanna ti,

   Nwon ni l’ojo Pentikost‘. 

Egbe: Agbara yi, on kanna ti Jesu 

      Se ileri p'o mbo.


2. Awon enia ro pe,

   Nwon f’esu l’esu jade. 

Egbe: Agbara yi, on kanna...


3. Emi buburu kan ko 

   Tun le ri wa gbese mo. 

Egbe: Agbara yi, on kanna...


4. Aje ko le ri wa mo, 

   Oso ko ri wa gbese. 

Egbe: Agbara yi, on kanna...


5. Eni f 'okan fun Jesu

   On ni yio ri igbala. 

Egbe: Agbara yi, on kanna...


6. Emi agbara otito

   Nwon ti nse Metalokan. 

Egbe: Agbara yi, on kanna...


7. B’a ba f’ori ti d’opin 

   Ere nla yio je tiwa 

Egbe: Agbara yi, on kanna...


8. Gbat' iku ara ba de 

   Emi y’o je t'Olorun 

Egbe: Agbara yi, on kanna...


9. Ekun, ose, a koja

   Gbat’ a ba r‘Olugbala 

Egbe: Agbara yi, on kanna...


10. Halle Halle Halleluya, 

    Yio j’orin wa lojo na.

Egbe: Agbara yi, on kanna ti Jesu 

      Se ileri p'o mbo. Amin

English »

Update Hymn