HYMN 175

1. A nri adun ninu ikoro

   A nrin l’opopo ona 

   Awon t’a gbala y’o ma korin 

   A rin l’opopo ona.

Egbe: Opopo ona si orun

      Biti ‘banuje nfo lo

      Imole nIa si ntan nibe

      A nrin l’opopo ona.


2. Awa y'o ri ogo Oluwa 

   A nrin l’opopo ona 

   Ati ewa oro mimo Re 

   A nrin l’opopo ona. 

Egbe: Opopo ona si orun...


3. Opo ojo ibukun y'o ro

   A nri |'opopo ona

   Y’o je isun om’iye fun wa 

   A nrin l’opopo ona 

Egbe: Opopo ona si orun...


4. Alaimo ki y’o koja nibe 

   A nrin l’opopo ona

  Ona na fun awon mimo ni 

  A nri l’opopo ona.

Egbe: Opopo ona si orun...


5. Ko si eru fun wa l‘ona na

   A nrin l'opopo ona

   Ko s‘eru f'awon t’a rapada

   A nrin l’opopo ona.

Egbe: Opopo ona si orun

      Biti ‘banuje nfo lo

      Imole nIa si ntan nibe

      A nrin l’opopo ona. Amin

English »

Update Hymn