HYMN 176

(FE 194) Tune: K & S 1871. lYIPADA 'yanu l’aye mi lati se 

   Gba Jesu wonu okan mi

   Imole nla ti de ti mo nwa kiri. 

Egbe: Gba Jesu wonu okan mi

      Gba Jesu wonu (wonu) okan mi 

      Gba Jesu wonu (wonu) okan mi 

      Odo ayo nsan I 'okan mi b'igbi okun 

      Gba Jesu wonu okan mi.


2. Mo ti f’opin si ‘rinkiri ati sina 

   Gba Jesu wonu okan mi

   Ese mi to si po lati fonu kuro 

   Gba Jesu wonu okan mi.

Egbe: Gba Jesu wonu...


3. Mo ni reti kan to ni idaniloju

   Gba Jesu wonu okan mi

   Ko sohun to le mu mi siyemeji mo 

   Gba Jesu wonu okan mi.

Egbe: Gba Jesu wonu...


4. Erni yo si ma gba ni ‘lu na ti mo mo 

   Gba Jesu wonu okan mi

   lnu mi si ndun, mo si nyo bi mo ti nlo

   Gba Jesu wonu okan mi.

Egbe: Gba Jesu wonu okan mi

      Gba Jesu wonu (wonu) okan mi 

      Gba Jesu wonu (wonu) okan mi 

      Odo ayo nsan I 'okan mi b'igbi okun 

      Gba Jesu wonu okan mi. Amin

English »

Update Hymn