HYMN 182

C.M.S 34 H.C 66 P.M (FE 200) 
"O to wakati ati ji I’oju orun"
- Rom. 13:111. GBO ohun alore 

   Ji, ara, ji

   Jesu ma fere de 

   Ji, ara, ji

   Omo oru ni nsun 

   Omo imole l'enyin 

   Ti nyin l‘ogo didan 

   Ji, ara ji.


2. So f’egbe t’o ti ji 

   Ara, sora

   Ase Jesu daju 

   Ara, sora

   Ese b’olusona 

   N'ilekun Oluwa nyin, 

   Bi o tile pe de,

   Ara, sora.


3. Gbo ohun Iriju, 

   Ara. sise
 
   Ise na kari wa, 

   Ara sise,

   Ogba Oluwa wa,

   Kun fun ‘se n‘gbagbogbo 

   Y‘o si fun wa lere

   Ara sise.


4. Gb’ohun Oluwa wa,

   E gbadura 

   B’e fe k' inu Re dun

   E gbadura,

   Ese mu ‘beru wa, 

   Alailera si ni wa, 

   Ni ijakadi nyin

   E gbadura.


5. Ko orin ikehin

   Yin, ara, yin 

   Mimo ni Oluwa

   Yin, ara, yin 

  Kil'o tun ye ahon 

  T'o fere b'angeli korin

  T'y'o r'Oloru titi

  Yin ara, yin. Amin 
 

English »

Update Hymn