HYMN 185

C.M.S. 72 t.S 22 S.M (FE 203) 
"Gbogbo oju ni yio si ri" - Ifi. 1:71. ONIDAJO mbo wa 

   Awon oku jinde 

   Enikan ko yo kuro 

   ‘Nu imole oju Re.


2. Enu ododo Re 

   Yio da ebi fun

   Awon t'o so anu Re nu 

   Ti nwon se buburu.


3. 'Lo kuro lodo mi 

   S’ina ti ko l‘opin

   Ti a ti pese fun Esu 

   T’o ti nsote si mi.


4. lwo ti duro to!

   Oju na o mbo wa

   T‘aiye at‘orun o fo lo

   Kuro ni wiwa Re. Amin

English »

Update Hymn