HYMN 190

C.M.S 51 H.C 72 t.s 219 
L.M - Ps. 102:201. OJO ‘binu ojo eru 

   T’aiye at’orun y‘o fo lo 

   Kin'igbekele elese

   Y‘o se le yoju l'ojo na?


2. Nigbati orun y‘o kako 

   Bi awo ti a fi ina sun 

   T‘ipe ajinde y‘o ma dun 

   Kikankina, teruteru.


3. A! l'ojo na, ojo ‘binu

   T eda yio ji si dajo 

   Kristi, jo ji si dajo

   ‘Gba t’ayie t'orun ba fo lo. Amin

English »

Update Hymn