HYMN 191

C.M.S. 70 t, H.C 73. 8s. 7s 4 
(FE 209)1. WO! Oluwa l'awosanma 

   O mbo l'ogo l'ola Re, 

   Enit‘ a pa fun elese

   Mbo pelu Angeli Re 

   Halleluyah!

   Halleluyah!


2. Gbogbo eda, wa wo Jesu

   Aso ogo I'a wo fun

   Awon t‘o gan, a won t'o pa 

   T‘o kan mo Agbelebu

   Won o sokun

   Bi nwon ba ri Oluwa.


3. Erekusu. okun, Oke, 

   Orun, aiye, a fo lo

   Awon t‘o ko a da nwon ru 

   Nigbati nwon gb'ohun Re 

   Wa s'idajo

   Wa s‘idajo, wa kalo!


4. lrapada t'a ti nreti

   O de pelu ogo nla 

   Awon ti a gan pelu re, 

  Yio pade Re loj‘orun! 

  Halleluyah!

  Ojo Olugbala de. Amin

English »

Update Hymn