HYMN 195

(FE 214)
"otito ni gbogbo oro Re" Ps. 119:1601. GBOGBO agbaiye e wa gb‘oro Jesu

   On ni Oluwa t‘o le gba ‘raiye

   Omo Ogun Kristi, e tun ona Re se 

   Jesu Oluwa mbo wa, joba l‘aiye. Int


2. Enyin Hausa, e wa gb‘oro Jesu

   On ni Oluwa t‘o le gba ‘raiye

   Omo Ogun Kristi, e tun ona Re se 

   Jesu Oluwa mbo wa, joba l‘aiye. Int


3. Eni ‘rapada, e wa gb‘oro Jesu

   On ni Oluwa t‘o le gba ‘raiye

   Omo Ogun Kristi, e tun ona Re se 

   Jesu Oluwa mbo wa, joba l‘aiye. Int


4. Enyin lmale, e wa gb‘oro Jesu

   On ni Oluwa t‘o le gba ‘raiye

   Omo Ogun Kristi, e tun ona Re se 

   Jesu Oluwa mbo wa, joba l‘aiye. Int


5. Gbogbo ayanfe, e wa gb‘oro Jesu

   On ni Oluwa t‘o le gba ‘raiye

   Omo Ogun Kristi, e tun ona Re se 

   Jesu Oluwa mbo wa, joba l‘aiye. Int Amin

English »

Update Hymn