HYMN 20

(FE 37)
E.O. 16, C.M.S 488 6. 6 7. 6. 7. 6.
"Ojo keje li Ijo isimi Oluwa
Olorun re" - Eks 20:10


1. OSE, Ose rere,

   lwo ojo simi;

   O ye k’a fi ojo kna, 

   Fun Olorun rere,

   B‘ojo mi ba m’ekun wa, 

   lwo n’oju wa nu;

   Iwo ti s'ojo ayo,

   Emi fe dide re.


2. Ose, Ose, rere

   A ki o sise loni

  A o f'ise wa gbogbo 

  Fun aisimi ola,

  Dldan l'oju re ma dan 

  ‘Wo arewa ojo

  Ojo mi nso ti lala, 

  Iwo nso Ii ‘simi.


3. Ose. Ose, rere

   Ago tile nwipe 

   F'Eleda re l’ojo kan, 

  T'O fun wa n’ljo mefa 

  A o fi ‘se wa sile

  Lati lo sin nibe

  Awa ati ore we,

  Ao lo sile adua.


4. Ose, Ose, rere 

   Wakati re wu mi, 

   Ojo orun ni ‘wo se 

   ‘Wo apere orun 

   Oluwa, je ki njogun

   ‘Simi lehin iku

   Ki nle ma sin O titi, 
   
   Pelu enia Re. Amin

English »

Update Hymn