HYMN 200

H.C 91 87. 8.7.8. 7.8.7
“Awa wa lati foribale fun u" 
-Matt. 2:21. ENYIN Angel’ l’orun ogo, 

   To yi gbogbo aiye ka;

   E ti korin dida aiye,

   E so ti‘ ibi Messia;

Egbe: E wa josin, e wa josin, 

      Fun Kristi Oba titun.


2. Enyin Oluso - agutan, 

   Ti nso eran nyin loru, 

   Emmanueli wa ti de, 

   Irawo Omo na ntan.

Egbe: E wa josin...


3. Eyin Oluso-aguntan,

   Ti n so eran yin loru

   Emmanueli wa ti de,

   Irawo omo naa n tan.

Egbe: E wa josin...


4. Elese 'wo alaironu,

   Elebi ati egbe, 

   Ododo Olorun duro, 

   Anu npe o, pa ‘wa da.

Egbe: E wa josin...


5. Gbogbo eda e fo f'ayo, 

   Jesu Olugbala de, 

   Anfani miran ko si mo, 

   B’eyi ba fo yin koja.

Egbe: E wa josin, e wa josin, 

      Fun Kristi Oba titun. Amin

English »

Update Hymn