HYMN 203

C.M.S84 HC 88. 88. 8s. (FE 222) 
“Nwon o ma pe oruko re ni 
Emmanuel” - Matt. 1:231. AYO kun okan wa loni, 

   A bi Omo Oba!

  Opo awon ogun orun, 

  Nso ibi Re loni.

Egbe: E yo, Eyo, Olorun d' enia, 

      O wa joko I'aiye,

      Oruko wo l' o dun to yi 

      Emmanuel.


2. A wole n’ ibujee eran, 

   N’iyanu l’ a josin: 

   lbukun kan to ta 'yi yo,

   Ko s‘ ayo bi eyi. 

Egbe: E yo, Eyo, Olorun...


3. Aiye ko n‘ adun fun wa mo, 

   ‘Gbati a ba nwo O: 

   L’owo Wundia Iya Re,

  ‘Wo Omo Iyanu.

Egbe: E yo, Eyo, Olorun...


4. Imole lat’ inu “Mole, 

   Tan ‘mole s'okun wa; 

   K' a le ma fi isin mimo, 

   Se‘ ranti ojo Re.

Egbe: E yo, Eyo, Olorun d' enia, 

      O wa joko I'aiye,

      Oruko wo l' o dun to yi 

      Emmanuel. Amin

English »

Update Hymn