HYMN 204

C.M.S 83 K. 39 t.H.C. 113 C.M. 
"Oluwa joba" - Ps. 97:11. AYO b’aiye! Oluwa de; 

   K’ aiye gba Oba re;

   Ki gbogbo okan mura de, 

   K'aiye korin soke.


2. Ayo b’aiye! Jesu joba, 

   E je ‘ Ka ho f’ ayo; 

   Gbogbo igbe, omi, oke, 

   Nwon ngberin ayo na.


3. K'ese on ‘yonu pin l'aiye, 

   K’ egun ye hun n' ile;

   O de lati mu 'bukun san, 

   De’bi t'egun gbe de.


4. O f‘ oto at‘ ife joba, 

   O jek’ Oril’ ede,

   Mo ododo ljoba Re, 

   At' ife ‘iyanu Re. Amin

English »

Update Hymn