HYMN 206

C.M.S. 81 H.C. 87. 7s. (FE 225) 
"Nitori a bi omo kan fun wa"
- Isa. 9:61. GBO, eda orun nkorin: 

   “Ogo fun Oba t'a bi“ 

   “Alafia laiye yi,

   Olorun ba wa laja, 

   Gbogbo eda nde layo; 

   Dapo mo hiho orun;

   W‘ Alade Alafia! 

   Wo, Orun ododo de.


2. O bo'go Re s‘apakan; 

   A bi k’enia ma ku; 

   Abi k‘ o’gb’enia ro;

   A bi k‘ o le tun wa bi. 

   Wa, ireti enia

   Se ile Re ninu wa 

   N'de, lru omobinrin 

   Bori esu ninu wa.


3. Pa aworan Adam run;

   F' aworun Re s’ipo re;

   Jo masai f’ Emi Re kun, 

   Okan gbogbo’ onigbagbo, 

   “Ogo fun Oba t’ a bi” 

   Jeki gbogbo wa gberin; 

   "Alafia laiye yi"

   Olorun ba wa laja. Amin

English »

Update Hymn