HYMN 210

C.M.S 90 H.C. 9. D. 7s.6s.
"Bakanna ni Iwo, Odun re ko I’opin."
 - Ps. 102:27
1. APATA aiyeraiye, 

   Enit’ o mbe lailai,

   Nigbakugba t’iji nla, 

   ‘Wo ‘bugbe alafia; 

   Saju dida aiye yi, 

   lwo mbe, bakanna, 

   Tit' aiaye ainipekun, 

   Aiyeraiye ni ‘Wo.


2. OJ’ odun wa ri b’oji, 

   T' ohan l‘ori oke; 

   Bi koriko ipado,

   T' o ru ti o si ku;

   Bi ala; tabi b’ itan, 

   T‘ enikan nyara pa; 

   Ogo ti ko ni si mo, 

   Ohun t’ o gbo tan ni.


3. ‘Wo eniti ti togbe, 

   ‘Mole enit’ itan:

   Ko wa bi ao ti ka,

   Ojo wa koto tan; 

   Jek‘anu Re ba le wa,

   K‘ ore Re po fun wa; 

   Si jek’ Emi Mimo Re, 

   Mole si okan wa.


4. Jesu, f‘ ewa at’ ore, 

   De'gbagbo wa l’ ade; 

   Tit’ ao fi ri O gbangba, 

   Ninu mole lailia;

   Ayo t'enu ko le so, 

   Orisun akunya, 

   Alafia Ailopin; 

   Okun ailebute. Amin

English »

Update Hymn