HYMN 214

H.C. 111 6s. 8s. (FE 233) 
"O ti ran mi lati kede idasile" - Isa. 61:!1. E funpe na kikan, 

   lpe ihinrere,

   K’ odun jake jado, 

   L’ eti gbogbo eda;

Egbe: Odun idasile ti de; 

      Pada elese e pada.


2. Fun ‘Pe t' Odagutan; 

   T‘ a ti pa s'etutu, 

   Jeki agbaiye mo, 

   Agbara eje Re.

Egbe: Odun idasile...


3. Enyin eru ese, 

   E so ‘ra nyin d' omo, 

   Lowo Kristi Jesu, 

   Egb’Ominira nyin.

Egbe: Odun idasile...


4. Olori Alufa, 

   L‘Olugbala ise;

   O fi ‘ra Re rubo 

   Arunkun, aruda. 

Egbe: Odun idasile...


5. Okan alare, wa, 

   Simi l‘aya Jesu, 

   Onirobinuje, 

   Tujuka, si ma yo.

Egbe: Odun idasile ti de; 

      Pada elese e pada. Amin

English »

Update Hymn