HYMN 22

C.M.S 489, H.C 489, S.M (FE 39)
“E sunmo Olorun...On yio si
sunmo nyin” - Jak. 4:8


1. JESU, a w’odo Re

   L’Ojo Re mimo yi, 

   To wa bi awa ti pejo 

   Si ko wa fun ‘ra Re.


2. Dari ese ji wa,

   Fun wa l’Emi Mimo 

   Ko wa k’ihin je ibere 

   Aiye ti ko l’opin.


3. F'ife kun aiya wa,

   Gba ‘se oluko wa; 

   K‘awa at' awon le pade 

   Niwaju Re l'oke. Amin

English »

Update Hymn