HYMN 220

1. ORE-OFE Baba, ati t‘Omo Re 

   Ore-ofe Emi, metalokan lai

   My iyin wa funwa ati imole

   O le okunkun lo, o nm‘okan wa yo.

Egbe: Ore-Ofe Olorun si wa iyanu ni 

      Ope ore-ofe Re wa nibi gbogbo 

      Ore-ofe nla ti' nfo gbogbo eda mo 

      Wa to ebun ofe wo, ore-ofe nla.


2. Nibiti ese po, or'ofe njoba 

   Itan ‘yanu l‘eyi, to sowon pupo 

   Mase so ‘reti nu, ore‐ofe nsan 

   O ga ju orun lo, o jin ju okun.


3. A nf‘ ore-ore yi, lo gbogb’enia 

  We, iwo t'eru, y’o gbe won fun 

  Enika to wa, a ki y’o tanu 

  Yio fe o lofe, ma siyemeji. Amin

English »

Update Hymn