HYMN 222

C.M.S 96 C.M (FE 241)
"Je ki ise Re ki o han si awon omo
odo Re" - Ps. 90:161. OLORUN at' ireti mi 

   Oro Re l‘onje mi

   Owo Re gbe mi ro l’ewe 

   Ati l’odomode.


2. Sibe mo rohun iyanu 

   ‘O nse ni ododun 

   Mo fi ojo mi ti o ku 

   S’iso Tire nikan.


3. Ma ko mi, nigba‘agbara ye 

   Ti ewu ba bo mi

   Ki ogo Re ran yi mi ka 

   Nigbati mo ba ku. Amin

English »

Update Hymn