HYMN 223

C.M.S. 92 H.C. 279 C.M (FE 242) 
“Olorun, Iwo Ii o ti nse ibujoko wa 
lati irandiran" - Ps. 90:11. OLORUN t’odun t’o koja 

   Iret’eyi ti mbo

   Ib’isadi wa ni iji

   At’ile wa lailai.


2. Labe ojiji ite Re,

   L’ awon enia Re ngbe! 

   Tito l‘apa Re nikansoso 

   Abo wa si daju.


3. K’awon oke k’o to duro 

   Tabi k’a to d’aiye 

   Lailai Iwo ni Olorun 

   Bakanna, ailopin.


4. Egbegberu odun l’oju Re, 

   Bi ale kan l’ori

   B’iso kan l’afemojumo 

   Ki orun k’o to la.


5. Ojo wa bi odo sisan

   Opo l’o si ngbe lo

   Nwon nlo, nwon di eni’gbagbe 

   Bi ala ti a nro.


6. Olorun t'odun t'o koja 

   Iret'eyi ti mbo

   Mas‘abo wa ‘gba 'yonu de, 

   At'ile wa lailai. Amin

English »

Update Hymn