HYMN 23

C.M.S 490, H.C 490, CM. (FE 40)
“Omiran si bo si ile rere, mo si so 
eso" - Matt.13:8


1. K’AWA to pari eko wa,

   Awa f’ iyin fun O

   T’ori ojo Re mimo yi, 

   Jesu, Ore ewe.


2. Gbin oro Re si okan wa, 

   Gba wa lowo ese

   Ma je k’a pada lehin Re, 

   Jesu, Ore ewe.


3. Jesu jo, bukun ile wa, 

   K’a lo ojo yi ‘re 

   K’a le ri aye lodo Re, 

   Jesu, Ore ewe. Amin

English »

Update Hymn