HYMN 230

Tune: DCM “Baba Niwaju ite Re”1. ODUN miiran tun ti de 

   Ona t’a ko rin ri

   Yoo fun mi ni ikilo 

   B’iranlowo ko si 

   Sugbon Eni t’O to mi 

   Ni odun t’o koja

   Se ‘leri p’Oun yoo duro 

   Ti mi nigba gbogbo.


2. Odun mii pelu Jesu 

   Emi ko mo ‘foya 

   Yebiye ni ife Re

   B'o ti wu k’iji le 

   Gba t'iji ba tile le 

   No sinmi ninu Re 

   No r’alaafia didun 

   Ni ookan aya Re.


3. Odun ti n o gbekele E 

   N o tun gbekele I'Eni 

   Ti koja mi kule ri

   Gba ti mo n wo’oju Re 

   O f’ogo at'opa Re 

   Fun mi, fun okun mi 

   Jeejee l’O si n to mi lo 

   L‘ona mi lo s'ile.


4, Odun miiran lnti sin in 

   Ki n s‘ise fun un nihin 

   Gba l’ojiji tile gun 

   Orun tun n sunmo le

   N ko mo gba ti yoo pe mi 

   Lati f'ise sile

   je ki n le je olooto 

   B’ojo ti n sure lo.


5. Odun miiran lati fe E 

   Eni ti mo feran

   Odun miiran lati yin in 

   Pelu orin segun 

   Ohun t’ola le mu wa 

   Banuje tab'iya

   lfe Re duro laelae 

   Okan naa ni titi.


6. Odun mii pelu Jesu

   Oluwa mo dupe 

   F‘oju Re ti ki i kuna 

   L’ona ajo aye

   Joo maa to mi, Oluwa 

   Ko mi ki n se ‘fe Re

   Si mu ete ti Re se

   L‘aye mi l’ojoojo. Amin

English »

Update Hymn