HYMN 235

SS/S 5 (By W Sorrow) (FE 255)
“Gbo ohun mi, Oluwa" - Ps. 27:71. MO ri ayo n’nu banuje 

   Ogun fun irora

   Mo r’ojo nla t'o dara 

   T’o ran lehin ojo

   Mo ri’ran lehin ojo 

   Mo r’eka ‘mularada 

   Nibi isun ki ikoro 

Egbe: lleri jeje t’a se

      Fun eniti njaya,

      lleri jeje t’a se

      Fun eniti njaya.


2. Ninu irin ajo mi

   Mo ba Jesu pade

   Ti o f‘okan mi bale 

   Lati ri anu gba

   Anu ti nko Ie gbagbe 

   lf‘aiya bale nla. 

Egbe: lleri jeje t’a se...


3. Mo ti ri sinu ese 

   Fitila mi ku tan 

   Nipa anu Olorun 

   Mo d’eniti nsoji 

   Anu re ra mi pada 

   O fl ireti fun mi. 

Egbe: lleri jeje t’a se...


4. Enyin Egbe Serafu

   Ejo ma jafara

   E je ka damure wa 

   K'ina wa si ma tan 

   Amure ko gbodo tu

   lna ko gbodo ku 

Egbe: lleri jeje t’a se

      Fun eniti njaya,

      lleri jeje t’a se

      Fun eniti njaya. Amin

English »

Update Hymn