HYMN 236

C.M.s.187 H.C.117 t.S 43 (FE 256) ss 97
"Ba mi yo, mo ri aguntan mi." - Luku 15:6
Tune: lpile ti Jesu fi lele1. MOKANDILOGORUN dubule je

   Labe oji nin’agbo 

   Sugbon okan je lo or'oke 

   Jina s’ile ilekun wura 

   Jina rere l'or oke sisa 

   Jina rere s‘OIus’aguntan.


2. 'Mokandilogorun Tire leyi 

   Jesu, nwon ko ha to fun O? 

   Olus’agutan dahun, 'Temi yi, 

   Ti sako lodo mi

   B'ona tile ri palapala

   Ngo w’aginju lo w'agutan mi.


3. Okan nin‘ awon t"ara pada 

   Ko mo jinjin omi na

   Ati duru oru ti Jesu koja 

   K’o to r‘agutan re he 

   L’aginju rere I’o gbo 'gbe re 

   O ti ri tan, o si t ku tan.


4. Nibo n’iro eje ni ti wa

   To fona or‘oke han?

   ‘A ta sile f’enikan t’o sako 

   K’Olusagutan to mu pada 

   Jesu, kil' o gun owo Re be? 

   ‘Egun pupo l'o gun mi nibe.


5. Sugbon ni gbogbo pori oke 

   At l'ori apata

   lgbe ta l’ooke orun wipe 

   “Yo, mo r’agutan ni he" 

   Y’ite ka l’awon angel ngba 

   'Yo, Jesu m‘ohun Tire pada. Amin

English »

Update Hymn