HYMN 242

(FE 262)
C.M.S. 142 T. t. H.C 246 SM 
"Jesu sokun” - John 11:351. KRISTI sun f‘elese 

   Oju wa o gbe bi? 

   K‘omi ronu at‘ikanu 

   Tu jade l'oju wa.


2. Omo Olorun nsun 

   Angeli siju wo!

   K‘o damu, iwo okan mi 

   O d’omi ni fun o.


3. O sun k’awa k‘o sun

   Ese bere ekun

   Orun nikan ni ko s’ese 

   Nibe ni ko s'ekun. Amin

English »

Update Hymn