HYMN 243

C.M.S 143 H.C 54 8 t.H.C 191 
8.7 (FE 263)
"Loto, emi ti gbo Efraimu npohunrere 
ara re” - Jer. 31:181. OLUWA, ma moju kuro 

   L'odo emi t'o nyi'e 

   Ti nsokun ese aiye mi 

   N‘ite anu ife Re.


2. Ma ba lo sinu dajo

   Bi ese mi ti po to 

   Nitori mo mo daju pe 

   Emi ko wa lailebi.


3. lwo mo, ki nto jewo re 

   Bi mo ti nse laiye mi 

   At‘iwa isisiyi mi 

   Gbogbo re l'O kiyesi.


4. Emi ni f'atunwi se 

   Ohun ti mo fe toro

   Ni iwo mo ki nto bere 

   Anu ni lopolopo.


5. Anu Oluwa ni mo fe 

   Eyi l'opin gbogbo re 

   Tori anu ni mo ntoro 

   Jeki nri anu gba. Amin

English »

Update Hymn