HYMN 244

CM.S 144 H.C 147 C.M (FE 264) 
"E je ki a fi igboiya wa si ibi ite 
ore-ofe:" - Heb. 4:161. OKAN mi sunmo ‘te anu 

   Nibi Jesu ngb’ebe 

   F’irele wole l’ese Re, 

   'Wo ko le gbe nibe.


2. Ileri Re ni ebe mi

   Eyi ni mo mu wa

   lwo npe okan t’eru npa 

   Bi emi Oluwa.


3. Eru ese wo mi l'orun 

   Ese use mi n‘ise 

   Ogun I'ode, eru ninu 

   Mo wa isimi mi.


4. Se Apata at' Asa mi 

   Ki nfi O se abo

   Ki ndoju ti Olufisun 

   Ki nso pe Kristi ku.


5. Ife Iyanu! Iwo ku

   Iwo ru itiju

   Ki elese b‘iru emi 

   Le be I'oruko Re. Amin

English »

Update Hymn