HYMN 246

C.M.S 149 H.C 155 t.H.C 94.
S.M. (FE 266)
"Awon sokun nigbati awa ranti 
Sioni" - Ps. 132:11. JlNA s’ile orun

   S'okan aiya Baba

   Emi ‘bukun wa, mo ndaku 

   Mu mi re ‘bi simi.


2. Mo fi duru mi ko 

   S'Ori igi willo

   Ngo se korin ayo, gbati 

   'Wo koi t’ahon mi se.


3. Emi mi lo sile

   A! mba le fo de 'be

   Ayun re nyun mi ‘wo Sion 

   Gba mo ba ranti re.


4. Sodo re mo nt’ona

   T'o kun fun isoro

   “Gbawo ni ngo koj' aginju 

   De ‘le awon mimo?


5. Sunmo mi, Olorun
  
   'Wo ni mo gbekele

   Sin mi la aginju aiye

   Ki m'de ‘le nikehin. Amin

English »

Update Hymn